Take a fresh look at your lifestyle.

Ìgbìmọ̀ ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ ti fagilé ìwé-àṣẹ Àwọn ilé-iṣẹ́ ìròyìn Méjìlélàádọ́ta lorílẹ̀dè Nàìjíríà.

0 271

Àjọ tó n mójú tó ètò ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti kéde láti fagilé àwọn ìwé-àṣẹ tí o fún ni lánfààní láti ṣiṣẹ́ ti Africa Independent Television (AIT), Raypower FM, Silverbird tẹlifisiọnu, àti Rhythm FM, láàrin àwọn ilé-iṣẹ́ ìròyìn mìíràn, pẹ̀lú ti aladani àti ti ìjọba.

Ní bi àpéjọ àpérò kan ní ìlú Abuja ní ọjọ́ Jimọ, Olùdarí Gbogbogbò ti Ìgbìmọ̀, Mallam Balarabe Shehua Ilelah ṣàlàyé pé idi ti wọ́n fi fagilé àwọn ilé-iṣẹ́ wọnyi ni pé àilè san owó àtúnṣe ìwé-àṣẹ iṣẹ́ wọn nyi àkókò lẹ́yìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìkìlọ̀.

Ọláyinká Akíntọ́lá.

Leave A Reply

Your email address will not be published.