Take a fresh look at your lifestyle.

Wilder kéde Ìjà Ẹ̀sẹ́ Kíkàn àkọ́kọ́ Rẹ̀ Lẹ́yìn Ìgbà tí ó Ti pàdánù Sọ́wọ́ Fury

0 142

Ògbóntagìrì Olúbori afẹ̀sẹ́kù tẹ́lẹ̀ rì nì, Ọ̀gbẹ́ni Deontay Wilder yóò pada wọ̀yá ìjà pẹ̀lú Tyson Fury kí ọdún yìí tó parí eléyìí tííse àkọ́kọ́ lẹ́yìn ìjà ẹ̀kẹta pẹ̀lú rẹ̀

Ará Amẹ́ríkà náà yóò kojú Robert Helenius ti Finland ní gbọ̀ngàn Barclays ti Brooklyn ní ọjọ́ kẹrìn dín lógún, Oṣù Kẹwàá.

Ipele kọkànlá ni Fury ti fi ẹ̀sẹ́ kíkàn rẹ̀ bìí Wilder wó lulẹ̀ ní Osù Kọkànlá Ọdún tó kọjá tí ó sì gba bẹ́lítìì WBC àseyọrí ìdíje náà.
Wọ́n yẹ́ẹsí pẹ̀lú ère rẹ̀ ní Tuscaloosa, Alabama ní ìbẹ̀rẹ̀ ọdún yìí .

 

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Leave A Reply

Your email address will not be published.