Take a fresh look at your lifestyle.

Fẹ́mi Gbàjàbíàmílà Náà Báwọn Dásí Àwo Orin ‘Bùgá’

0 104

Agbenusọ ti Ilé Ìgbìmọ̀ Asojú Sòfin ti Nàìjírìà náà ti báwọn dási ìpènijà ti bùgá tí ònkọrin gbajúgbajà tí a mọ̀ sí Kizz Daniel kọ tí àwon ènìyàn má ǹ gbé pòyì ẹnu nínú orin ní ọjọ́ Ọjọ́bọ̀ nígbàtí ó báwon jó ijó Bùga ní Sùrúlérè ní ibi ìpàdé kan.

 

Ó fi àkókò náà gba àwọn ènìyàn ní ìmọ̀ràn láti lọ gba káàdì alálòpẹ́ ìdìbò wọn kí wọ́n leè kópa nínú ìdìbò tó ń bọ̀.

 

 

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Leave A Reply

Your email address will not be published.