Oǹkọ̀wé orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Olùdarí Bíyìí Bándélé di olóògbé
Eyitayọ Fauziat Oyetunji
Oǹkọ̀wé orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Olùdarí Bíyìí Bándélé di olóògbé
Oǹkọ̀wé,olùkọ eré orí ìtàgé àti olùdarí ere Half Of a Yellow Sun àti tí ó tún jẹ́ olùdarí pẹ̀lú àwọn mìíràn fún eré Blood Sisters, Bíyìí Bándélé ti jẹ́pè olúwa.
Gẹgẹ bi alaye kan ti o jade loju-iwe Facebook rẹ nipasẹ ọmọbinrin rẹ, Temi Bandele ni ọjọ Aje.
“Gẹgẹ bi Ọmọbinrin Biyi ṣe sọ, pẹlu ibanujẹ ni mo fi kede iku ojiji ati iku airotẹlẹ baba mi Biyi Bandele ni ọjọ keje,ọjọ abamẹta, Oṣu Kẹjọ, ni Ilu Eko,” o fi ṣe akọle.
Biyi Bandele jẹ ọmọ bibi orilẹ-ede Naijiria ti o n gbe ni Ilu Gẹẹsi, onkọwe ati oṣere fiimu. O ko lọ si orilẹ ede Lọndọnu ni ọdun 1990.
Leave a Reply