Take a fresh look at your lifestyle.

2023: Olùdíje ipò ààrẹ Ẹgbẹ́ ṣèpàdé pẹ̀lú Aṣojú Amẹ́ríkà ní Nàìjíríà

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 60

Lọ́jọ́ Ìṣẹ́gun, olùdíje fún ipò Ààrẹ ẹgbẹ́ Labour, Peter Obi, ṣe ìpàdé pẹ̀lú aṣojú orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà ní Nàìjíríà, William B. Stevens.

Gómìnà ìpínlẹ̀ Anambra tẹ́lẹ̀ rí sọ èyí  lórí Tiwita rẹ,tí ó fìdí ẹ múlẹ̀ ní ọjọ́rú.

O sọ pe awọn ṣe ijiroro pataki ati ti awọn si gbara awọn nimọran lakoko ipade naa.

Peter Obi sọ pe oun sọ erongba  orilẹ-ede Naijiria tuntun oun, aabo, iṣọkan, eyiti yoo wa si imuṣẹ bi oun ba jawe olubori fun idije ipo aarẹ, pẹlu aṣoju orilẹ-ede Amẹrika.

Leave A Reply

Your email address will not be published.