Àjọ tí í ṣe àkọ́so àwọn agùnbánirọ̀ ti ṣe ìdásílẹ̀ ètò tí yóò ma mójútó àwọn agùnbánirọ̀.
Àtẹ̀jáde yíi w’áyé láti ẹnu olùdarí àti alukoro fún àjọ agúnbánirò, Ọgbẹni Eddy Megwa.
Nínú àtẹ̀jáde yíi, Olùdarí àgbà fún àjọ agùnbánirọ̀, Mohammed Fadah, sọ wípé iṣẹ̀ ẹgbẹ́ náà ni láti tẹ̀síwájú ní gbígba ìròyìn àti ọ̀rọ̀ tó ń lọ lóri irinṣẹ́ ayélujára,fún ìmójútó to péye, pẹ̀lú yíyára sí iṣẹ́ ní kíákíá fún àwọn agùnbánirọ̀ lẹ́nu iṣẹ́ ẹ wọn àti àkókò ìpàdá wọn.
Oyèbísí Adégbìté
Leave a Reply