Take a fresh look at your lifestyle.

A ó fi àjọ ECOWAS sílẹ̀ nítorí ìwà ojú-sàájú-Ahmed Idris Wase

0 211

Orílẹ̀ èdè Nàíjíríà ti ní òun yóò  kúrò láti máa jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́  ajọ ilẹ alawọ dúdú iyẹn , Economic Community of West African States (ECOWAS).

Ipe yii waye latari bi  àwọn adarí àjọ ohun se ń  se ojú saaju si bi wọn se n gba awọn mọlẹbi ati ibatan wọn sẹnu isẹ .

Asoju orilẹ ede Naijiria  ní ile igbimọ asofin ní ECOWAS tó wà nílùú  Abuja, ti o tun jẹ igbakeji adari ilé igbimọ asofin ti ajọ ECOWAS, Ahmed Idris Wase lo sọrọ nibi ipade ti ajọ  ile igibmọ asofin ECOWAS  se lọdun 2022. pé, ó tí di dandan ki orilẹ ede Naijiria se atunyẹwo lori ipò rẹ̀ ati jíjẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ ECOWAS.

 

 

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button