Take a fresh look at your lifestyle.

2023:Olùdarí àgbà VON Ṣọ àsọtẹ́lẹ̀ Ìṣẹ́gun Tinúubú ní ìdá ọgọ́ta nínú ọgọ́rùn ún

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 78

Olùdarí Àgbà fún Voice of Nigeria, VON, Osita Okechukwu, sọ pé olùdíje fún ipò Ààrẹ ẹgbẹ́ All Progressives Congress, APC, Ọ̀gbẹ́ni Bọ́lá Tinúubú, yóò borí nínú ìdìbò ọdún 2023, ní ìdá ọgọ́ta nínú ogórùn ún.

Ogbẹni Okechukwu lo sọ eleyi nigba to n ba awọn oniroyin sọrọ nilu Abuja.

VON DG, ti o ṣe ayẹwo agbara Ọgbẹni Tinubu, sọ pe nitori pe APC ni o n ṣakoso awọn ipinlẹ mejile-logun, Ọgbẹni Tinubu ni anfani ti o pọ julọ lati jawe olubori.

Ogbeni Okechukwu, soro nipa pataki pinpin ati iwọntun wọnsi agbara fun isokan Naijiria,o tun mẹnuba ifẹ rẹ fun Ọgbẹni Tinubu lati yan ẹlesin igbagbọ Ariwa gẹgẹ bi igbakeji oludije.

Leave A Reply

Your email address will not be published.