Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Muhammadu Buhari ti fi ìkíni ọ̀yàyà ránṣẹ́ sí Gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkó, Babajide Sanwo-Olu, ní ọjọ́ ayẹyẹ ọjọ́ ìbí ọdún kẹtàdínlọ́gọ́ta.
Ààrẹ Buhari síì yọ̀ pẹ̀lú aṣáájú òṣèlú náà lórí àwọn iṣẹ́ tóti ṣe níné iṣẹ́ àdáni àti ti gbogbogbòò.
Ọláyinká Akíntọ́lá.
Leave a Reply