Take a fresh look at your lifestyle.

Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà já sí ipò kọkànlélọ́gbọ̀n nínú Ipò FIFA.

0 212

Ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Super Eagles ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti tàdí sẹ́yìn nínú ipò tuntun FIFA nítorí wọ́n ti di ẹgbẹ́ kọkànlélọ́gbọ̀n tí ó dára jùlọ ní ipò oṣù kẹfà ti FIFA gbéjáde.

Nàìjíríà jẹ́ ọgbọ̀n ẹgbẹ́ tó dára jù lọ lágbàáyé nínú ìpele oṣù kẹta.

https://help.twitter.com/en/twitter-for-websites-ads-info-and-privacy

Síbẹ̀síbẹ̀, ẹgbẹ́ Jose Peseiro jẹ ẹgbẹ́ kẹrin tí ó dára jùlọ ní Áfíríkà lọ́wọ́lọ́wọ́, lákòókò tí Àwọn kìnìún Teranga ti Senegal jẹ́ nọ́mbà àkọ́kọ́ ní Áfíríkà àti méjìdínlógún tí ó dára jùlọ ní àgbáyé.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button