Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Muhammadu Buhari ti bọwọ́lu àbádòfin ètò ìlera mádamidófò

0 66

Ààrẹ Muhammadu Buhari ti buwọ́lu ìwé òfin ètò ìlera mádamidófò ti ọdún 2022 láìpẹ́ yìí.

Ààrẹ náà kéde pé àjọ náà yóò fọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú àwọn ètò ìdánilẹ́kọ̀ọ́ ìlera ti ìjọba ìpínlẹ̀ láti fọwọ́ sí dídásílè ilé ìwòsàn alábọ́dé àti ti ìpínlẹ̀ àti láti fi àwọn ọmọ Nàìjíríà sínú ètò náà.

Aláàkóso náà sọ pé fọwọ́sowọ́pọ̀ náà yóò mú kí ètò àbò múnádóko.

 

Ọláyinká Akíntọ́lá

Leave A Reply

Your email address will not be published.