Igbimọ Alase ijọba apapọ (FEC) ti fọwọsi idoko-owo aladani ti o le ni ọgọjọ bilioni naira (N169) fun awọn atunse opopona nipasẹ eto owo-ori ti ijọba orilẹ-ede Naijiria.
Minisita fun eto ise ati ile, Babatunde Fashola lo soro yii lasiko to n ba awon oniroyin soro ni ile ijọba lẹyin ipade ọsẹsẹ ti igbimọ to waye ni ile igbimọ ni aafin aarẹ, ni ilu Abuja
Aare Muhammadu Buhari lo dari ipade naa.
Leave a Reply