Take a fresh look at your lifestyle.
Democracy

Minamino Mi Ikọ̀ Southampton Tì Tì

0 72

Bákan náà lọmọ́ sorí fún ikọ̀ Southampton. Ìyà tó gbóná ni ikọ̀ Liverpool fi jẹ wọ́n níwájú àwọn olólùfẹ́ wọn pẹ̀lú àmì ayò 2-1.

Bo tilẹ jẹ pe awọm ogbongẹ atamatase ikọ Liverpool bi Sadio Mane, Mohammed Salah ati Luiz Diaz ko kopa ninu ifẹsẹwọnsẹ naa, awọn to soju wọn ko gbẹyin rara.

Ọmọ Southampton ni, Redmond lo kọkọ daya ja ikọ Liverpool nigba ti o jẹ goolu ni isẹju kẹtala. Ko pẹ rara ni Minamino da pada, lo ba di 1-1. Joel Matip lo fi ade de lori pẹlu goolu kejui fun ikọ Liverpool.

Pẹlu esi ifẹsẹwọnsẹ yi, opin ija fi ife ẹyẹ idijẹ “English Premier League” laarin ikọ Liverpool ati ikọ Manchester City da ọjọ Abamẹta ti idijẹ naa fun saa ti a wa yi yoo wa si opin.

Leave A Reply

Your email address will not be published.