Take a fresh look at your lifestyle.
Democracy

Ikọ̀ Newcastle United Kọ Ojú Arsenal Sí Òrùn Ọ̀sán Gangan; Ìdíje UEFA Champions League Bọ́ Mọ́ Wọn Lọ́wọ́!

0 70

Gbogbo akitiyan Arsenal lati kopa ninu idije “UEFA Champions League” fun saa ti o n bọ ti ja si pabo latari bi ikọ Newcastle United se da erupẹ si gaari wọn.

Ami ayo meji si odo (2-0) ni wọn ko le wọn lọwọ. Saka, atamatase Arsenal ti fi ẹdun ọkan rẹ han; o sọ pe awọn ko se daadaa rara. Xhaka, ẹni ti o jẹ balogun fun wọn sọ wipe wọn ko yẹ fun ẹni ti o n kopa ninu idije UEFA Champions League.

Leave A Reply

Your email address will not be published.