Take a fresh look at your lifestyle.

Ọ̀ṣun 2022: Ọ̀gọ̀ọ́rọ́ Àwọn Olólùfẹ́ PDP ń Yípadà sí APC Ní ìjọba ìbílẹ̀ Ayédáadé

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 193

Ipò ẹgbẹ́ òṣèlú alátakò pàtàkì nípínlẹ̀ Ọ̀sun, People’s Democratic Party, PDP, ti dín kù gan-an nígbà tí ó lé ní ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta [500] lára ​​àwọn ọmọ ẹgbẹ́ rẹ̀ ló ti kéde pé àwọn fẹ́ dara pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressive Congress, APC, ní ìjọba ìbílẹ̀ Ayedade ní ìpínlẹ̀ náà ṣaájú  ìdìbò gómìnà ọjọ́ kẹrìndín-lógún, Oṣù Keje.

Awọn aṣofin naa sọ pe, awọn iwọnba aṣeyori ti ẹgbẹ oṣelu Gomina Adegboyega Oyetọla ti ṣe laarin ọdun mẹta ati idaji sẹyin, lo jẹ ki awọn ṣe ipinnu naa.

Awọn aṣaaju ẹgbẹ oṣelu APC nipinlẹ naa ṣe sọ pe iyapa apapọ naa jẹ itọka si otitọ pe ẹgbẹ naa yoo jawe olubori ninu ibo gomina to n bọ.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button