Take a fresh look at your lifestyle.

NGO ṣe ìfilọ́lẹ̀ Ilé-akéde fún oko dídá ní Nàìjíríà

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 182

Láti ṣe àlékún ìṣelọ́pọ̀ àgbẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Ẹgbẹ́ tí kìí ṣe tìjọba (NGO), ti ṣe ìfilọ́lẹ̀ ilé-akéde asọ̀rọ̀mágbèsì fún iṣẹ́ ọ̀gbìn  láti dé ọ̀dọ̀ àwọn àgbẹ̀ ní àwọn agbègbè ìgbèríko lórí àwọn iṣé-ọ̀gbìn tí ó dára jùlọ.

Nigba ti o n sọrọ pẹlu awọn ti o nii ṣe ni akoko ifilọlẹ  ile-akede asọrọmagbesi naa ni ilu Abuja, Oludari eto, Farm Radio International Initiatives (FRI), Ian Pringle, sọ pe eyi waye latari ati maa fun awọn eniyan   nimọ,ikede  ati atilẹyin awọn iyipada rere ni eka iṣẹ-ogbin.

Bakannaa, Pringle sọ pe idagbasoke naa yoo koju awọn adanu to maa n waye lẹyin ikore , mu jije mimu  dara si,mu iduroṣinṣin igbelaruge aabo ounje  ati ti  oniruuru ounjẹ ti awọn ọmọ orilẹ-ede Naijiria n pese ati n jẹ yoo si tun dara si.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button