Take a fresh look at your lifestyle.

Málì yọwọ́ kúrò ní ìgbógun ti ẹkùn Jihadist

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 163

Ilé-ìgbìmọ̀ ìjọba Málì sọ pé òun yóò jáwọ́ lórí  ipa gbígbógun ti jihadist  Iwọ̀-oòrùn Áfíríkà, lẹ́yìn tí ó ti dínà mọ láti gba ipò Ààrẹ ẹgbẹ́ agbègbè náà.

Bi orilẹ-ede naa ṣe kuro labẹ  aabo G5 Sahel ni o tunbọ jẹ ki ipinya rẹ jinlẹ si  lẹyin ti awọn orilẹ-ede ti wọn jọ pin aala jẹniya ni Oṣu Kini nipa bi wọn ṣe n fi dida ijọba pada si tiwantiwa falẹ.

Ibatan ọgbọn iṣelu orilẹ-ede Mali pẹlu awọn alajọṣepọ rẹ iwọ-oorun, pẹlu agbara amunisin tẹlẹ Faranse,wa lara nnkan to ba orile-ede naa jẹ, ni pataki julọ ibawi aipẹ pẹlu Rọsia.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button