Take a fresh look at your lifestyle.

Gómìnà Tambuwal dín ìséde oní Wákàtí mẹ́rìnlé-lógún kù Ní Ìpínlẹ̀ Sókótó

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 203

Ní Àtẹ̀lé ìfitónilétí kan nípasẹ̀ Àwọn olórí Ààbò ní Ìpínlẹ̀ Sókóto,́ Gómìnà Àmínù Wàzírì Tambuwal, ti pàṣẹ láti dín ìséde oní wákàtí -lógún ọ̀hún kù ní  Ìpínlẹ̀ náà.

Ilana isede ti wọn tun gbeyẹwo yoo jẹ lati aṣalẹ si owurọ (6am-6pm) ni ilu Sokoto.

Ninu atẹjade  Kọmisana fun eto iroyin ni Sokoto, Isah Bajini,agbeyẹwo naa wa pelu erongba lati fun awon eniyan ni anfaani lati ṣọrọ aje wọn ati awon ọna atijẹ atimu miran.

Àmọ́ ìjọba náà wá gba àwọn ará ìlu nímọ̀ràn pé, kí wọ́n máa wà ní àlàáfíà lórí ọ̀rọ̀ yìí, torí pé kò ní fàyè gba ẹnikẹni to ba rufin àti ìlànà ní Ìpínlẹ̀ náà.

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.