Take a fresh look at your lifestyle.
Democracy

Liverpool fa aṣọ iyì Chelsea ya nígbà tí wọ́n jáwé olúborí nínú ìdíje FA CUP

0 64

Ẹgbẹ́ agbábọ̀ọ̀lù Chelsea bá Liverpool fa kàngbọ̀n lóri pápá, nígbàtí kò sí ẹni tó mi àwọ̀n nínú wọn tí wọ́n fi parí.

Liverpool ṣẹ̀dá àwọn àyè tó dára jùlọ ní ìdajì akọ́kọ́ pẹ̀lú Luis Diaz lọ́pọ̀lọpọ̀ ìgbà, ṣaájú kí Chelsea tó padà wá ní ìdajì kejì, pẹ̀lú Alonso.

Lẹ́yìn tí ẹgbẹ́ agbábọ̀ọ̀lù méjèjì ti fi yé ara wọn pé ọ̀gá làwọn méjèjì, ni wọ́n bá kọrí sí èyí tí àwọn olóyìnbó pèní penalty kick, ibẹ̀ni Liverpool ti lu Chelsea ní àmi àyò mẹ́fà sí máàrún tí wọ̀n sì gba ife FA Cup ní ọjọ́ Sátidé.

 

Ọláyinká Akíntọ́lá.

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.