Take a fresh look at your lifestyle.

Igbákejì Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàíjiríà bu ẹnu àtẹ́ lu pípa ọmọ ilé ìwé ní ìpínlẹ̀ sokoto

0 414

Igbákejì Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàíjiríà, Ọ̀jọ̀gbọ́n Yemi Osinbajo ti fèsì sí ikú ọmọ ilé ìwé Shehu Shagari College of Education, ìpínlẹ̀ Sokoto, ó se àpèjúwe ìṣẹ̀lẹ̀ náà gẹ́gẹ́ bi èyí tí kò bójúmu.

Deborah Samuel, ọmọ ilé-ìwé ti ilé-ẹ̀kọ́ náà ni wọ́n pa nípasẹ̀ àwọn ènìyàn láabi kan ní ọjọ́bọ̀ fún ẹ̀sùn ìsọ̀rọ̀ lòdì sí ànábì Muhammad (SAW).

Ọ̀jọ̀gbọ́n Osinbajo sọrọ, ósì bu ẹnu àtẹ́ lu ìṣẹ̀lẹ̀ náà ní àyè ààrẹ ti Pápákọ̀ òfurufú Nnamdi Azikiwe ní ọjọ́ọ Jímọ̀.

 

Ọláyinká Akíntọ́lá.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button