Take a fresh look at your lifestyle.

Mo ṣèlérí láti ran Orílẹ̀-èdè south sudan lọ́wọ́ – Aarẹ Muhammadu Buhari

0 135

Ààrẹ Muhammadu Buhari ti ṣèlérí pé orílẹ̀-èdè Nàìjíríà yóò ran orílẹ̀-èdè South Sudan lọ́wọ́ láti gbógun ti ìwà ipá, àti dídá ìṣọ̀kan padà bọ́ sípò ní orílẹ̀-èdè náà.

Ààrẹ ṣe àdéhùn yìí ní ọjọ́ Jímọ̀ ní Ilé-ìgbìmọ̀ Ìpínlẹ̀, Abuja, lákòkóò tí ó ngba àwọn olùgbó, aṣojú pàtàkì Ààrẹ Salva Kiir Mayardit ti orílẹ̀-èdè South Sudan, Ọ̀gbẹ́ni Albino Mathom Ayuel.

Ó sọ ipò tí ìṣákóso rẹ̀ bá nílẹ̀ ní agbègbè àríwá-ìwọ̀ orùn ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní ọdún 2015 fún aṣojú pàtàkì South Sudan.

 

Ọláyinká Akíntọ́lá

Leave A Reply

Your email address will not be published.