Take a fresh look at your lifestyle.

Àwọn Gómìnà orílẹ̀-èdè Russia mẹ́rin kọ̀wé fiṣẹ́ sílẹ̀ nítorí ìjẹníyà

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 38

Àwọn gómìnà agbègbè mẹ́rin ní orílẹ̀-èdè Russia ti fi ipò sílẹ̀ ní ọjọ́ Ìṣẹ́gun, bí orílẹ̀-èdè náà ṣe ń gbaradì lati mú ìdàgbàsókè ètò ọrọ̀-ajé wọn.

Àwọn olori  agbegbe Tomsk, Saratov, Kirov ati Mari El ti kede ifiṣẹ silẹ wọn lẹsẹkẹsẹ, ti olori agbegbe Ryazan si sọ pe oun ko ni kopa fun sáà miiran.

Wọn yan awọn gomina agbegbe  Russia,ti wọn si wa labẹ iṣelu Kremlin. Ọpọlọpọ awọn gomina to jẹ aṣoju awọn agbegbe nibi ti ẹgbẹ ijọba United Russia ti ni awọn ipin ibo ti ko pọ ni awọn idibo ile-igbimọ ni ọdun to kọja.

Wọn maa n yọ Awọn gomina ti ko ṣe daradara kuro ni ọfiisi wọn

Leave A Reply

Your email address will not be published.