Ààrẹ obìnrin àkọ́kọ́ orílẹ̀-èdè Hungary, Katalin Novak,wọṣẹ́ ní ọjọ́ Ìṣẹ́gun.
Ile aṣofin yan Novak gẹgẹ bi Aarẹ orilẹ-ede Hungary ni ọjọ kẹwaa, Oṣu Kẹta,lẹyin idibo rẹ, Novak sọ pe oun fẹ jẹ Aarẹ alafia.
Ayẹyẹ ibura yoo waye ni owurọ ọjọ abamẹta, ni Kossuth Square, ni iwaju Ile-igbimọ.