Olori ile-iṣẹ ologun, Lieutenant General Faruk Yahaya ti kepe awọn ologun ti wọn ti fẹyìntì lẹnu isẹ lati ma se lọra nipa sisọ awọn imọran ati iroyin ti o le jẹ anfani lati koju awọn ipẹnija ti o n yọ orilẹ ede Naijiria lẹnu lẹka aabo.
General Yahaya sọ eyi ni ọjọ Isẹgun ,ọjọ kẹwa Oṣu Karun, ọdun 2022 nibi apejọ kan ti o da lori igbaradi awọn ọmọ ologun.
Leave a Reply