Take a fresh look at your lifestyle.

Adelabu Fi Èròǹgbà Rẹ̀ Hàn Fún Ipò Gómìnà Ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́

0 28

Igbakeji gomina ile ifowopamọsi apapọ ti Naijiria (CBN) tẹlẹri ati oludije fun ipo gomina nigba kan ri ninu ẹgbẹ oselu APC ni ipinlẹ Ọyọ lọdun 2019, Oloye Adebayo Adelabu ti sọ pe oun setan lati dije du ipo gomina ipinle naa, nigba keji, lori pèpéle ti ẹgbẹ oselu APC.

Adelabu sọrọ yii lọjọ Aje to kọja nigba to n ba awọn oniroyin sọrọ, nibi to ti fẹsun kan Gomina Seyi Makinde pe lati igba ti o ti gori oye ni iwa jijagidijagan, iwa ibajẹ ati ipaniyan ti peleke si ni ipinlẹ naa.

O sọ pe oun yoo mu oun gbogo pada bọ sipo ti wọn ba le dibo yan oun gẹgẹ bi gomina ipinlẹ naa.

Leave A Reply

Your email address will not be published.