Take a fresh look at your lifestyle.

Premier League: Ẹgbẹ́ Agbábọ̀ọ̀lù Tottenham bá Ẹgbẹ́ Agbábọ̀ọ̀lù Liverpool wọ̀ yàá àjà

0 41

Ẹgbẹ́ Agbábọ̀ọ̀lù Liverpool jìyà ńlá ní ìrètí rẹẹ̀ láti gba ipò kìnńí ní Premier League sùgbọ́n ófihàn pé ti wọn kọ́, nígbàtí wọ́n gba bọ́ọ̀lù kòsí ẹni tó jù 1-1 pẹ̀lu ẹgbẹ́ agbábọ̀ọ̀lù Tottenham.

Eré ni ẹgbẹ́ agbábọ̀ọ̀lù  Liverpool pèé, àfi bí SON ọmọ ẹgbẹ́ agbábọ̀ọ̀lù Tottenham se mi àwọ̀n ní ìsẹ́jú mẹ́rìndìnlọ́gọ́ta, tí DIAZ ọmọ ẹgbẹ́ agbábọ̀ọ̀lù liverpool náà dápadà fún wọn ní ìsẹ́jú mẹ́rìnléníààdọ́rin.

Èyí lógbé ẹgbẹ́ agbábọ̀ọ̀lù Tottenham bọ́sí ipò kẹrin lóóri tábìlì premier league.

 

Ọláyinká Akíntọ́lá.

Leave A Reply

Your email address will not be published.