Take a fresh look at your lifestyle.

Ikọ̀ Liverpool Àti Ikọ̀ Real Madrid Yóò ti Ẹsẹ̀ Bọ Sòkòtò Kan Fún Ifẹ Ìdíje UEFA Champions League

0 43

Látàrí bí ikọ̀ Real Madrid se móríbọ́ nínú ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ tí wọ́n ní pẹ̀lú ikọ̀ Machester City pẹ̀lú àmì ayọ̀ 6-5; áwọn pẹ̀lú ikọ̀ Liverpool ni yoo jọ waaya ija, ti wọn yoo si fi ẹsẹ bọ inu sokoto kan ni ilu Paris, Orilẹ ede Faranse, ni ọjọ kejidinlọgbọn ọṣu Karun.

 

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.