Take a fresh look at your lifestyle.

WAFCON 2022: Ẹgbẹ́ Agbábọ̀ọ̀lù Orílẹ́-ẹ̀dè Nàìjíríà yóò kojú Ẹgbẹ́ Agbábọ̀ọ̀lù South Africa, Burundi àti Botswana

0 48

Ẹgbẹ́ Agbábọ̀ọ̀lù àgbà àwọn obìnrin Orílẹ́-ẹ̀dè Nàìjíríà, Super Falcons, yóò kojú South Africa, Burundi ati Botswana ní Group C ti ìdíje àwọn obìnrin Áfíríkà ti 2022 ni Ilu Morocco.

Mohamed VI Complex ní ìjọba àríwá Áfíríkà ti gbàlejò àwọn ìdíje WAFCON, èyítí ó sọ àwọn ẹgbẹ́ méjìlá tí ó yege fún Ife àwọn obìnrin Áfíríkà kejìlá sí ẹgbẹ́ mẹ́ta ti ẹgbẹ́ mẹ́rin kọọ̀kan.

https://twitter.com/NGSuper_Falcons/status/1520146543613030400?ref_src=twsrc%5Etfw%7Ctwcamp%5Etweetembed%7Ctwterm%5E1520146543613030400%7Ctwgr%5E%7Ctwcon%5Es1_c10&ref_url=https%3A%2F%2Fvon.gov.ng%2F2022%2F04%2F29%2Fwafcon-2022-nigeria-to-face-south-africa-burundi-botswana%2F

Nàìjíríà gba ife ẹ̀yẹ AFCON Obìnrin ní ọdún 1998, 2000, 2002, 2004, 2006, 2010, 2014, 2016 àti 2018. Ṣùgbọ́n, wọ́n  fagilé ìdíje ti ọdún 2020 nítorí àjàkálẹ̀-ààrùn COVID-19. Equatorial Guinea gba ìdíje náà ní ọdún 2008 àti 2012, ṣùgbọ́n wọ́n kùnà láti dé òpin ìparí ọdún yìí.

https://twitter.com/CAFwomen/status/1520158663490551810?ref_src=twsrc%5Etfw%7Ctwcamp%5Etweetembed%7Ctwterm%5E1520158663490551810%7Ctwgr%5E%7Ctwcon%5Es1_c10&ref_url=https%3A%2F%2Fvon.gov.ng%2F2022%2F04%2F29%2Fwafcon-2022-nigeria-to-face-south-africa-burundi-botswana%2F

 

Ọláyinká Akíntọ́lá

Leave A Reply

Your email address will not be published.