Take a fresh look at your lifestyle.

Ẹgbẹ Awọn Oṣiṣẹ Orílẹ̀-ẹ̀dè Nàìjíríà ṣe ìwọ́de fún àjọ̀dún àwọn òṣìṣẹ́

0 245

Gẹ́gẹ́bí ara àwọn ètò  láti se àjọ̀dún àwọn òṣìṣẹ́ ti ọdún yìí, Ẹgbẹ́ Òṣìṣẹ́ Nàìjíríà ti ṣe ìwọ́de àgbáyé lati fi ẹ̀hónú wọn hàn lóríi àwọn ẹ̀tọ́ wọn díẹ̀ ni Orílẹ́-ẹ̀dè Nàìjírìa.

Ìwọ́de náà wáyé láti Ilé-ìgbìmọ̀ òṣìṣé tó wà ní àárín agbègbè, Abuja, lọ sí ilẹ́-iṣẹ́ Ìjọba àpapọ̀ pẹ̀lú àwọn aláṣẹ àjọ tó mójútó ètò ìrìnà àti àwọn aṣojú ààbò mìíràn láti ríi dájú pé ó lọ ní ìrọwọ́ rosè.

Wọ́n sì ké gbàjarè sí ìjọba láti tètè wá ojútùú sí ètò àbò Orílẹ́-ẹ̀dè Nàìjíríà.

 

Ọláyinká Akíntọ́lá

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button