Take a fresh look at your lifestyle.

Orílẹ̀èdè Nàìjíríà Wà Ní Digbín, Kò Sì Le Subú Lulẹ̀

0 321

Ìjọba Nàìjíríà  sọ pé àsọtẹ́lẹ̀  pé orílẹ̀èdè Nàìjíríà yóò ṣubú lulẹ̀ jẹ́ òfúùtù-fẹ́ẹ̀tẹ̀, asán póńbélé.

Agbẹnusọ fún Ààrẹ, Garba Shehu, nínú àtẹ̀jáde kan, sọ pé àsọtẹ́lẹ̀ náà kìí ṣe nkànkan bíkòṣe èrò ọkàn tàbí àfokànsùn orílẹ̀ èdè Àmẹ́ríkà.

Shehu sọ pe bo tilẹ jẹ pe wotowoto  n jẹyọ lori isubu Naijiria lati ẹnu awọn ara ilu Amerika, ijọba yi wa ni digbin, ko si le subu.

 

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button