Take a fresh look at your lifestyle.

Owó rèé ọjà rèé

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 346

Ní báyìí àwọn awakọ̀ tó bá ti dúró ní Pápá ọkọ̀ òfurufú àgbáyé Nnamdi Azikiwe, Àbújá, Olú-ìlú Nàìjíríà yóò bẹ̀r̀ẹ sí ní máa sanwó.

Nigbati o n ba awọn ọmọ ẹgbẹ alaṣẹ awakọ ati eto ofurufu (ATACA), Alakoso Agba Ariwa aarin, Ọgbẹni Kabir Mohammed sọ pe erongba wọn fun eyi ni lati je ki eto ni  Papa ọkọ ofurufu Nnamdi Azikwe o gun rege.

Ọgbẹni Mohammed, tẹnumọ pe  eto  isanwo ni papa ọkọ ofurufu yoo koju awọn iṣoro agbero, eyiti o le da ọrọ-aje Ile-iṣẹ Ofurufu orile-ede gunlẹ tabi pa lara.

Bakan naa lo fi da awọn aririn ajo loju wi pe, papakọ ofurufu Nnamdi Azikwe ti n ṣiṣẹ bayii lori ona lati ya awon isowo ti ko bofin mu ti n waye ni iwaju gbọngan ijade ni papakọ ofurufu naa sọtọ gbangba.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button