Take a fresh look at your lifestyle.

Gómìná Ṣèyí Mákindé Kẹ́dùn Ikú Aláàfin Ọ̀yọ́, Ọba Làmídì Adéyẹmí III

0 91

Gómìná Mákindé, ẹni tí ó fi ìkíni ẹkú ará fẹ́rakù ránṣé sí ìgbìmọ̀ Ọ̀yọ́mèsì, ìdílée Ọba Làmídì Adéyẹmí III, àwọn ọmọ bíbí ìlú Ọ̀yọ́ àti gbogbo ọmọ Ilẹ̀ káàrọ́-ọ̀ jíire nígbàtí ó gbà ládùráà kí Ọlọ́run tẹ́ ẹ sáfẹ́fẹ́ rere.

Gómìná tún fi kún ọ̀rọ rẹ̀ pé, ìpínlè Ọ̀yọ́ ti pàdánù ọba alayé tó kún fún ìmọ̀ nípa àṣà àti ìṣe Ilẹ̀ káàró-ò jíre, tí ó sì mú àgbéga bá ipò aláàfin pẹ̀lú ìmọ̀ àti ọgbọ́n, eléèyí tí ó jé kí ó di àwòkọ́se rere fún àwọn ọba alayé ní ilẹ̀ aláwọ̀dúdú, eléèyí tí ó mú ògo bá ìpínlè Ọ̀yọ́ àti orílẹ̀ èdè Nàìjírìa.

Gómìná gbàá ládùráà kí Ọlọ́run Allah fi Aljanah Fridaus jinki Ọba Làmídì Adéyẹmí III.

 

Abiola Olowe
Ìbàdàn.

Leave A Reply

Your email address will not be published.