Take a fresh look at your lifestyle.
Democracy

ÌDÌBÒ ỌDÚN 2023: MÁA BÁÁ ISẸ́ RẸ̀ LỌ, OSINBAJO- OLÚBÀDÀN

0 234

Igbákejì Ààrẹ Orilè-èdè Nàìjírà, Ọ̀jọ̀gbọ́n Yemi Osinbajo ti  gba ìwúre lẹ́nu Ọba Olúbàdàn ti ìlú Ìbàdàn, Ọba Lekan Balogun pé kí ó máa bá isẹ́ rẹ̀ lọ lóri ètò ìdìbò ààrẹ tó ń bọ̀ ní ọdún 2023.

Igbákeji ààrẹ fi ẹsẹ̀ kan yà lọ kí Olúbàdàn ní ààfin, nígbà tí ó parí ìpàdé pèlú àwọn ọmọ ẹgbẹ́ òsèlú APC nínú Ìpàdé gbogbogbò tí ó wáyé ní ìlú Ìbàdàn.

 

Olúbàdàn ṣe ìwúre fún Igbákejì ààre wí pé yóò jáwé olúborí nínú ìdíje ààrẹ tó ń bọ̀ nígbà tí ó gba Igbákejì ààre lálejò pẹ̀lú àwọn olóyè rẹ̀, ààrẹ síì dúpẹ́ lọ́wọ olúbàdàn.

 

 

 

Ọláyinká Akíntọ́la

Leave A Reply

Your email address will not be published.