Take a fresh look at your lifestyle.

Ilé ìgbìmọ̀ Aṣojú Ṣèwádìí bí epo ilẹ̀ àti Gáásì fi gbówólérí

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 346

Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣojú  orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ti kàn án nípá fún ìgbìmọ̀ rẹ̀ lórí Àwọn orísun Epo ilẹ̀ àti ọ̀rọ̀ Gáásì láti ṣe ìwádìí ìgbówólórí epo ilẹ̀ àti gáásì ìdáná ní orílẹ̀-èdè láìpẹ́ yìí.

Awọn igbimọ naa ni lati wa ti owo awọn nnkan yii ṣe wa soke pẹlu ipinnu lati rii daju o pada si iye owo ti ko jara lọ,eyi ti yoo mu idinku ba ijiya awọn orilẹ-ede Naijiria.

Agbẹnusọ, Fẹmi Gbajabiamila pa aṣẹ naa lẹhin apero kan lori pataki lati ṣewadii ọrọ naa, ti wọn fọwọsi lapapọ.

Olugbowo eto naa, Chike Okafor lati Ipinlẹ Imo kerora lori iye owo epo ilẹ ti o wọn pupọ, nitori ọja ti wọn n ta laarin oogundin-lọọdunrun Naira si aadọtale-lọọdunrun fun lita kan ni ọsẹ mẹta sẹhin to wa jẹ pe lọwọlọwọ bayii i ti di ogundin-nigbaarin Naira fun lita kan.

Ọgbẹni Okafor ṣalaye ikcdun lori igbowolori epo ati gaasi naa.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button