Take a fresh look at your lifestyle.

Ìjọba Àpapọ̀ Bu Ọwọ́ Lu Àdéhùn (MOU) Pẹ̀lú Ilé-Iṣẹ́ Huawei Technologies Nigeria Limited Lórí Ìmọ̀-Ẹ̀rọ Ìbáraẹnisọ̀rọ̀

1 254

Ìjọba àpapọ̀ àti ilé-iṣẹ́ Huawei Technologies Nigeria Limited ti fọwọ́ sí ìwé àdéhùn kan (MoU) lórí Ìmọ̀-ẹ̀rọ Ìbáraẹnisọ̀rọ̀ (ICT) láti ṣe ìdánilẹ́kọ̀ọ́ àti  ìdánilókòwò fun ẹgbẹrun  òsìsẹ́ ìjọba jakejado orilẹ ede.

Akòwé Ìjọba àpapọ̀ Boss Mustapha, tí ó fọwọ́ sí àdéhùn náà, sọ pé èyí  ṣe àfihàn akitiyan Nàìjíríà láti wà ní  àjọṣepọ̀ pẹ̀lu okòwò aládáni.

1 Comment
  1. […] Tún kà nípa:Ìjọba Àpapọ̀ Bu Ọwọ́ Lu Àdéhùn (MOU) Pẹ̀lú Ilé-Iṣẹ́ Huawei Technolog… […]

Leave A Reply

Your email address will not be published.