Take a fresh look at your lifestyle.

Ó Mà Ṣe Ò! Everton Ti Dá Rafa Benitiez Dúró Lẹ́nu Iṣẹ́ Lẹ́yin Oṣù Méje

0 125

Oṣù kẹfà (June) ni ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù Everton gba Rafa Bennitez gẹ́gẹ́ bi akọ́nimọ̀ọ́gbá àti alákóso ikọ̀ náà. Àmọ́ o, láti ìgbà náà ní nǹkan ò ti sẹnu re fún ikọ̀ ńaà látàrí bí wọ́n sẹ fi ìdí rẹmi nínú ọ̀pọ̀lọ̀pọ̀ ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ tí wọ́n ti kópa nínu rè.

Ipò kẹrindinlogun (16th) ni wọ́n fìdí kalẹ́ sí nínú tábìlì ìdije “English Premier League”.

Waayi o, atamatase ikọ Everton tẹlẹri, ti o si ti fi igba kan jẹ alakoso ikọ Derby County, Wayne Rooney ni o dabi ẹni ti ifa Evẹrton yoo fi rọ́pọ̀ Rafa Benitez.

 

Tolulope Akinseye

Leave A Reply

Your email address will not be published.