Take a fresh look at your lifestyle.

Mùsè-Músé Manchester United Kò D́a Músé; Phillipe Coutinho Padà Wá Fìyà Jẹwọ́n     Aston Villa 2-2 Man United

0 100

Ikọ̀ Manchester United kò ì tíì jáwọ́ lọ́wọ́ ṣíṣe ségesège àti àìní ìforítì; èyí ló mú kí Ikọ̀ Aston Villa padà wá látẹ̀yì̀n wá dọ́gba pẹ̀lu wọn lẹ́yìn tí Bruno Fernandes atamátàsé Man United ti Fún wọn ní 2-0.

Ìṣéjú méjẹ péré ló gba Aston Villa láti gbá góàlì méjì sínú ààwọ̀n Man United. Ramsey pẹ̀lú P. Coutinho ló jẹ góàlì fún wọn ní ìsẹ́jú kẹ́tàdínlọ́gọ́rin (77th) àti ìsẹ́ju kẹrinlẹlọgọrin (84th).

 

 

Tolulope Akinseye

Leave A Reply

Your email address will not be published.