Take a fresh look at your lifestyle.

AFCON 2021: Ikọ̀ Agbábọ́ọ̀lù Algeria Ti Kan Ìdín Nínú Iyọ̀ Nígbà Tí Equatorial Guinea Fìyà Jẹwọ́n Pẹlu Ami Ayo 1-0

0 104

Ìsòro tí ikọ̀ Algeria wà nínú rẹ̀ ní ìdíje AFCON 202̀̀1 kò kéré rárá pẹ̀lú bí wọ́n se jẹ̀yà lọ́wọ́ Equatorial Guniea nínú ìfẹsẹ̀wọnsẹ́ ọjọ́ Àìkú.

Esi ifẹsẹwọnsẹ yii ti mu ki Algeria wa ni isale tabili bayii. Ti wọn ba fẹ tẹsiwaju ninu idije yii, wọn gbọdọ na ikọ Ivory Coast ninu ifẹsẹwọnsẹ kẹta ni ipẹlẹ kini, ni ipin E.

Leave A Reply

Your email address will not be published.