Take a fresh look at your lifestyle.
Democracy

Nigeria vs Sudan: Ikọ Super Eagles Nílò Láti Borí Ikọ̀ Sudan Láti Kógojá Sí Ipele Tó kànAFCON 2021

0 167

Ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù Super Eagles Nàìjíríà àti Ikọ̀ Sudan yóo  máa fẹsẹ̀ sínú sòkòtò kan lóòní ọjọ́ Àbámẹ́ta, ní déédé agogo márùn-ún ìrọ̀lẹ́, ní pápá ìṣiré Stade Roumdé Adijia tó wà ní ìlú Garoua lórílẹ̀ èdè Cameroun.

Orilẹ ede Naijiria lo wa loke tente tabili ipin D pẹlu ami mẹta lẹyin ti Sudan ati Guinea Bissau ta ọmi ẹlẹyin ti wọn si ni ami kọọkan.

Bi Sudan ba lee bori ifẹsẹwọnsẹ naa, ireti wa fun wọn lati  kogoja fun ipele to kan. Amọ ṣa, bi o ba jẹ Super Eagles Naijiria lo ba bori, a jẹ pe wọn kogoja fun ipele ẹlẹni mẹrindinlogun “round of 16” niyẹn.

 

 

.

 

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.