Take a fresh look at your lifestyle.

AFCON 2021: Ikọ̀ Super Eagles Na Sudan Bí Asọ Òkè Pẹ̀lú Àmì Ayò 3-1

0 103

Ní wàràǹsesà tí ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ náà ti bẹ̀rẹ̀ ni Super Eagles ti dáná sínú ààwọ̀n Sudan. Samuel Chukwueze, Taiwo Awoniyi pẹ̀lú Moses Simon ló jẹ goal fún ikọ̀ Supe Eagles.

Ikọ super Eagles ti sọ ara wọn da ẹru jẹjẹ ninu idijẹ AFCON pẹlu esi ifẹsẹwọnṣẹ yii. Waayi o, awọn pẹlu ikọ agbalejo, Cameroon ni o ti kogoja si ipilẹ onikọmẹrindinlogun (round of 16).

Irọlẹ Ọjọ Ọjọru ni ikọ Super Eagles yoo pade Guinea-Bissau.

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.