Take a fresh look at your lifestyle.

Quadri Dúpẹ́ Fún Àtìlẹyìn Aláìláfiwé

1 186

Ọba table tẹnisi ti Nàìjíríà Aruna Quadri ti dúpẹ́ lọ́wọ́ gbogbo àwọn olólùfẹ́ rẹ̀ fún àtìlẹ́yìn ńlá aláìláfiwé tí wọ́n fún u ní ọdun yìí.

Aruna ti o jẹ ọmọ ọdun mẹtalẹlọgbọn kọ eyi si ori ẹrọ instagram rẹ, lẹyin ti ọmọ orilẹ ede Brazil, Hugo Calderon nàá jade pẹlu ami ayo mẹta si ọ̀kan (3-1) ninu idije table tenis ti agbaye (WTT).
“Mo fẹ dupẹ lọwọ gbogbo awọn ololufẹ mi. Wọn jẹ ọkan ninu awọn idi ti mo ṣe n tẹsiwaju”

1 Comment
  1. […] Tún kà nípa:Quadri Dúpẹ́ Fún Àtìlẹyìn Aláìláfiwé […]

Leave A Reply

Your email address will not be published.