Take a fresh look at your lifestyle.

Orílẹ̀-Èdè South Korea Ṣe ìtorẹ Owó Tó Lé Ní Million Méjìlá Dólà Fún Orílẹ̀-Èdè Nàìjíríà láti Kọ́ Ẹ̀ro Amúnáwá Sólà

0 65

Ìjọba South Korea ti ṣe ìlérí láti pèsè owó tó lé ní million méjìlá dólà fún kíkọ́ àwọn ẹ̀rọ amúnáwá sólà sí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà

Aṣojú orílẹ̀-èdè Korea sí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Kim Young-Chae ló sọ èyí di mímọ̀ níbi Ìfilọlẹ̀ to waye ni ilu Abuja.

Ọgbẹni Young-Chae sọ pe iṣẹ akanṣe yi jẹ igbiyanju lati mu ilosiwaju de ba eto imo ẹro ati wipe lati ri daju wipe awon egberiko ti ina monamona ko i de jẹ anfaani ẹrọ sola yii

Leave A Reply

Your email address will not be published.