Take a fresh look at your lifestyle.
Democracy

Covid-19: Orílẹ̀-Èdè Nàìjíríà Tẹnumọ́ Akitiyan Láti Dẹkun Àrùn Còrónà

0 80

Nàìjíríà ti fi èròǹgbàa rẹ̀ hàn láti dẹ́kun àrùn Corona. Alákoso àgbà, Ahmed Lawan sọ èyí ní àpèjọ ọlọ́jọ́ méjì kan tó dá lórí fífòpin sí àrùn Corona, ní ìlú Abuja, lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà

Lawan ṣalaye pe oun to de ba oju lo de ba imu. Itumọ eyi nipe; bi ajakalẹ-arun naa ṣe kan ẹka ilera naa lo kan eto-ọrọ aje, koda gbogbo ẹka lokan lorilẹ-ede naa.

Bakan naa, o ṣe akiyesi pe pẹlu ifarahan titun ti Omicron, o ku ni mọ ro! Nitori naa awọn ọmọ orilẹede Naijiria ko gbọdọ sinmi nipa didekun atankalẹ ajakalẹ-arun naa.

Leave A Reply

Your email address will not be published.