Take a fresh look at your lifestyle.

FEC: Ḿinísítà fún Àwọn ọ̀dọ́ yóò Ṣàgbékalẹ̀ Àtẹ̀jáde NYSC kan lórí Owó Ìrànlọ́wọ́

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 74

Mínísítà fún Àwọn ọ̀dọ̀ àti Ìdàgbàsókè Eré-ìdárayá ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Sunday Dare, ti ṣe ìlérí láti ṣàgbékalẹ̀ ìwé-ákọọ́lẹ̀   fún ìdásílẹ̀ owó ìrànlọ́wọ́ fún àgùnbánirọ̀  (NYSC) fún  Ìgbìmọ̀ Alásẹ àpapọ̀ (FEC) ní ìlàsí mẹ́rin ọdún tó ń bọ̀.

Minisita naa sọ eyi lasiko ti o n ṣe afihan akọkọ iru rẹ ti akole rẹ jẹ, ‘ipe si iṣẹ ‘, ni Abuja ni ipari ọsẹ.

Leave A Reply

Your email address will not be published.