Take a fresh look at your lifestyle.

Àwọn ènìyàn márùnlé-láàdọ́ta míràn tún ti kó ààrùn corona

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 106

Àwọn ènìyàn márùnlé-láàdọ́ta míràn tún ti ní aarun corona.
ÀwÀwọn ènìyàn márùnlé-láàdọ́ta míràn tún ti ní aarun corona.
Ile-iṣẹ to n mojuto ajakalẹ aarun lorilẹ-ede NCDC sọ eleyii di mimọ lalẹ ọjọ aiku lori ayelujara fesibuuku rẹ
NCDC ṣalaye pe awọn eniyan wọnyii jẹyọ lati ipinlẹ mẹfa – “Lagos (mẹtadin-logoji), Edo (mẹfa), Osun (marun), Oyo (mẹrin), Ogun (meji), and Ekiti (ẹyọkan)”.
Lọwọlọwọ bayii awọn eniyan ẹ̀ẹ́dẹ́gbàta- le- ni- ọ̀kẹ́- mẹ̀wá abo- o -din- ni- èjì- din-  lọ́rin, ẹ̀ẹ́dẹ́gbàrin- le- n- lọ̀kẹ́- mẹ̀wá- o- le-ni- ọ́ta-din-lẹwá- din- lẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ́ta eniyan ti gba iwosan,ti okòó -din-  lẹgbẹ́ẹ́ẹdógún eniyan si ti jẹpe oluwa.

Leave A Reply

Your email address will not be published.