Take a fresh look at your lifestyle.

Ó lé ní mílíọ̀nù mẹ́ta ọmọ orílẹ̀ èdè Nàíjíríà, tó ti gba abẹ́rẹ́ àjẹsára COVID-19

0 159

Ó ti lé ní mílíọ̀nù mẹ́ta ọmọ orílẹ̀ èdè Nàíjíríà, tó ti gba abẹ́rẹ́ àjẹsára COVID-19 (3,938,945)  ni  kaakiri gbogbo ipinlẹ to wa ni jake-jado orilẹ ede Naijiria.

Eleyii jẹyọ ninu atẹjade kan ti awọn aosju -sofin orilẹ ede Naijiria  gbe wa si ile igbimọ aosju-sofin ti ilẹ Afirika, iyẹn ECOWAS  Parliament.

ọkan ninu ọmọ ile igbimọ asofin Lynda Chuba Ikpeazu, lo gbe atẹjade ọhun wa si ile-igbimọ asofin ti ilẹ Afirika.

Leave A Reply

Your email address will not be published.