Ijọba orilẹ ede Naijria ti fọwọsi gbigba abẹrẹ ajẹsara a-sara-lokun fun arun COVID -19 awọn eniyan ti wọn ti kọkọ gba abẹrẹ ajẹsara ti akọkọ ati ikeji , iyẹn abẹrẹ ajẹsara ti awọn ile-isẹ ti AstraZeneca, Moderna, Pfizer Bio-N-Techor1 ti Johnson & Johnson.
Faisal Shuaibwa tun tẹsiwaju nipa gbigba abẹrẹ ajẹsara a-sara-lokun fun arun COVID -19 yii:;
• Awọn eniyan ti iye ọmọ ọdun wọn ko ju ọdun mejidinlogun lọ.Any person 18 years and above.
• Awọn eniyan ti o ti to osu mẹfa ti wọn ti gba abẹrẹ ajẹsara COVID-19 ti ile-isẹ
AstraZeneca, Moderna tabi ti Pfizer Bio-N- se tabi ju bẹẹ lọ.
• Awọn eniyan ti o ti to osu meji ti wọn ti gba abẹrẹ ajẹsara COVID-19 ti ile-isẹ Johnson ati Johnson se tabi ju bẹẹ lọ.