Take a fresh look at your lifestyle.

South Sudan Yóó Fòpin Sí Ìgbéyàwó Ọmọ tí kò bàlágà

0 154

Ìjọba South Sudan ti ṣèlérí láti fòpin sí ìgbéyàwó  awọn ọmọ  ti ko bàlágà ní ọdún 2030 ní ìbámu pẹ̀lú ìpolongo ẹgbẹ́ Afirika láti fòpin síse ìgbéyàwó fun awọn ọmọ ti ọjọ́ ori wọn keré.

South Sudan jẹ ọkan ninu awọn orilẹ-ede ni agbaye pẹlu awọn oṣuwọn ti o ga julọ lori sise  igbeyawo fun ọmọ ti ọjọ́ ori wọn kere pupọ. Iwadii fihan pe lọdun 2010  awọn ọmọbirin ti ọjọ́ orí wọn ko to mẹẹdogun ni wọn s ṣe igbeyawofun .

Tolulope Akinseye

Leave A Reply

Your email address will not be published.