Take a fresh look at your lifestyle.

IKú dóró! Adarí ilé ìgbìmọ̀ asòfin tẹ́lẹ̀rì ,Wayas di olóògbé

0 206

Ààrẹ Muhammadu Buhari  ti bá ẹbí , ijọba ipinlẹ Cross River, ile igbimọ asofin agba ati  ọ̀rẹ́  adari ile igbimọ asofin tẹlẹri oloogbe Joseph Wayas dárò .

Asofin Joseph Wayas jẹ ọmọ ọgọrin  ọdun  nigba ti o dagbere fáyé pe o digbose .

Aarẹ Buhari tẹsiwaju pe orilẹ ede Naijiria mọrírih ipa pataki ti oloogbe naa ko lasiko ti o jẹ adari ile igbimọ asofin agba lorilẹ ede Naijria. Ọmọ ọdun mejidinlogoji ni  oloogbe Joseph Wayas lasiko ti o jẹ adari ile igbimọ asofin agba lorilẹ ede yii.

Aarẹ Buhari wa gbadura pe ki Ọlọrun tẹ́ oloogbe naa si afẹ́fẹ́ ire.

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.