Ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù Morocco bẹ̀rẹ̀ ìdíje FIFA Arab pẹ̀lú ọwọ́ agbára nígbà tí wọ́n fìyà tó nípon jẹ ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù Palestine
Mohammed Nahiri lo kọkọ si ifẹsẹwọnsẹ na loju nigba ti o mi àwọ̀n lẹyin ogoji iseju. Lẹyin naa ni Abdelilah Hafidi tun fọba lé àmì àkọ́kọ́ lẹẹmeji, ki Benoui Badr to pa oju re de, ki ifẹsẹwọnsẹ naa to pari.
Mẹarin si odo (4-0) ni ifẹsẹwọnsẹ na pari si, ti ikọ agbábọ́ọ̀lù Morocco si fi agba han ikọ Palestine
Leave a Reply